{
	"@metadata": {
		"authors": [
			"Demmy",
			"Diebuche"
		]
	},
	"wm-license-attribution-with-author-text": "Ẹni tó ni ẹ̀tọ́ àwòkọ fáìlì yìí, $1, gba ẹnikẹ́ni ní ààyè láti lòó fún ohunkóhun, lábẹ́ àdéhùn pé ẹni tó ni ẹ̀tọ́ àwòkọ yìí yíò jẹ́ dídálórúkọ bóbáṣẹyẹ. Ìtúnpínkiri, àtúnṣe sí, ìlò fún títà, àti gbogbo ọ̀nà ìlò mìràn jẹ́ gbígbà ní ààyè.",
	"wm-license-attribution-without-author-text": "Ẹni tó ni ẹ̀tọ́ àwòkọ fáìlì yìí gba ẹnikẹ́ni ní ààyè láti lòó fún ohunkóhun, lábẹ́ àdéhùn pé ẹni tó ni ẹ̀tọ́ àwòkọ yìí yíò jẹ́ dídálórúkọ bóbáṣẹyẹ. Ìtúnpínkiri, àtúnṣe sí, ìlò fún títà, àti gbogbo ọ̀nà ìlò mìràn jẹ́ gbígbà ní ààyè.",
	"wm-license-artwork-artist": "Oníṣọ̀nà",
	"wm-license-artwork-title": "Àkọlé",
	"wm-license-artwork-medium": "Ìfiṣọ̀nà",
	"wm-license-artwork-dimensions": "Ẹ̀gbẹ̀ẹ̀gbẹ́",
	"wm-license-artwork-current-location": "Ibùdó lọ́wọ́lọ́wọ́",
	"wm-license-artwork-object-history": "Ìtàn ohun yìí",
	"wm-license-artwork-references": "Àwọn ìtọ́kasí",
	"wm-license-artwork-inscriptions": "Àkọmọ́",
	"wm-license-artwork-notes": "Ìkíyèsí",
	"wm-license-artwork-id": "ID",
	"wm-license-artwork-source": "Orísun/Ayafọ́tò",
	"wm-license-book-edition": "Ìtúnṣe",
	"wm-license-book-editor": "Olùtúnṣe",
	"wm-license-book-illustrator": "Olùyàwòrán",
	"wm-license-book-language": "Èdè",
	"wm-license-book-page-overview": "Ìgbéwò ojúewé",
	"wm-license-book-place-of-publication": "Ibi ìtẹ̀jáde",
	"wm-license-book-printer": "Olùtẹ̀wé",
	"wm-license-book-publisher": "Olùtẹ̀jáde",
	"wm-license-book-series-title": "Àkọlé iṣẹ́ àdáléra",
	"wm-license-book-start-this-book": "Ìbẹ̀rẹ̀ Ìwé yìí",
	"wm-license-book-subtitle": "Àkọlé abẹ́",
	"wm-license-book-title": "Àkọlé",
	"wm-license-book-translator": "Olùyèdèpadà",
	"wm-license-book-volume": "Àkójọ",
	"wm-license-book-year-of-publication": "Ọdún ìtẹ́jáde",
	"wm-license-cecill-text": "Iṣẹ́ yìí jẹ́ [[{{int:wm-license-free-software-wiki-link}}|atòlànà kọ̀mpútà òfẹ́]]; ẹ le ṣàtúnpínkiri rẹ̀ tàbí ṣàtúnṣe rẹ̀ lábẹ́ àwọn ọ̀rọ̀ àdéhùn [[{{int:wm-license-cecill-wiki-link}}|CeCILL]]. Àwọn àdéhùn ìwé-áṣẹ CeCILL wà ní [{{int:wm-license-cecill-full-link}} www.cecill.info].",
	"wm-license-creator-alternative-names": "Àwọn orúkọ míràn",
	"wm-license-creator-description": "Ìjúwe",
	"wm-license-creator-date-of-birth": "Ọjọ́ ìbí",
	"wm-license-creator-date-of-birth-and-death": "Ọjọ́ ìbí/aláìsí",
	"wm-license-creator-location-of-birth": "Ibùdó ìbí",
	"wm-license-creator-location-of-birth-and-death": "Ibùdó ìbí/aláìsí",
	"wm-license-creator-work-period": "Ìgbà iṣẹ́",
	"wm-license-creator-work-location": "Ibi iṣẹ́",
	"wm-license-creator-linkback": "Àjápọ̀ padà sí àdàkọ àpótí-ọ̀rọ̀ Olùdá",
	"wm-license-fal-text": "Copyleft: Iṣẹ́ ọnà yìí jẹ́ ọ̀fẹ́; ẹ le ṣàtúnpínkiri rẹ̀ àti/tàbí ṣàtúnṣe rẹ̀ gẹ́gẹ́bí àwọn ọ̀rọ̀ àdéhùn '''[[{{int:wm-license-fal-wiki-link}}|Free Art License]]'''. Ẹ ó rìí àpẹrẹ ìwé-áṣẹ yìí lórí [{{int:wm-license-fal-full-link}} ibùdó Copyleft Attitude] àti lórí àwọn ibùdọ́ míràn.",
	"wm-license-gfdl-1.2-and-later": "Ìyọ̀nda wà láti ṣe àwòkọ, láti pínkàkiri àti/tàbí ṣ'àtúnse ìwé yìí l'ábẹ́ àwọn ọ̀rọ̀ àdéhùn '''[[{{int:wm-license-gfdl-wiki-link}}|GNU Free Documentation License]]''', Version 1.2 tàbí ìtẹ̀jáde ọjọ́ọwájú lát'ọwọ́ [[{{int:wm-license-fsf-wiki-link}}|Free Software Foundation]]; láìsí àwọn Ẹsẹ Aláìyàtọ̀, láìsí àwọn Ọ̀rọ̀-ìwé Níwájú, àti láìsí Ọ̀rọ̀-ìwé Lẹ́yìn. Àwòkọ ìwé àṣẹ náà jẹ́ sísopọ̀ mọ́ abala tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ ''[[{{int:wm-license-gfdl-full-1.2-link}}|GNU Free Documentation License]]''.",
	"wm-license-gfdl-1.2-only": "Ìyọ̀nda wà láti ṣe àwòkọ, láti pínkàkiri àti/tàbí ṣ'àtúnse ìwé yìí l'ábẹ́ àwọn ọ̀rọ̀ àdéhùn '''[[{{int:wm-license-gfdl-wiki-link}}|GNU Free Documentation License]]''', Version 1.2 gẹ́gẹ́bí wọ́n ṣe ti jẹ́ títẹ̀jáde lát'ọwọ́ [[{{int:wm-license-fsf-wiki-link}}|Free Software Foundation]] nìkan; láìsí àwọn Ẹsẹ Aláìyàtọ̀, láìsí àwọn Ọ̀rọ̀-ìwé Níwájú, àti láìsí Ọ̀rọ̀-ìwé Lẹ́yìn. Àwòkọ ìwé àṣẹ náà jẹ́ sísopọ̀ mọ́ abala tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ ''[[{{int:wm-license-gfdl-full-1.2-link}}|GNU Free Documentation License]]''.",
	"wm-license-gfdl-1.2-only-header": "1.2&nbsp;nìkan",
	"wm-license-gfdl-1.3-and-later": "Ìyọ̀nda wà láti ṣe àwòkọ, láti pínkàkiri àti/tàbí ṣ'àtúnse ìwé yìí l'ábẹ́ àwọn ọ̀rọ̀ àdéhùn '''[[{{int:wm-license-gfdl-wiki-link}}|GNU Free Documentation License]]''', Version 1.3 tàbí ìtẹ̀jáde ọjọ́ọwájú lát'ọwọ́ [[{{int:wm-license-fsf-wiki-link}}|Free Software Foundation]]; láìsí àwọn Ẹsẹ Aláìyàtọ̀, láìsí àwọn Ọ̀rọ̀-ìwé Níwájú, àti láìsí Ọ̀rọ̀-ìwé Lẹ́yìn. Àwòkọ ìwé àṣẹ náà jẹ́ sísopọ̀ mọ́ abala tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ ''[[{{int:wm-license-gfdl-full-1.3-link}}|GNU Free Documentation License]]''.",
	"wm-license-gfdl-1.3-only": "Ìyọ̀nda wà láti ṣe àwòkọ, láti pínkàkiri àti/tàbí ṣ'àtúnse ìwé yìí l'ábẹ́ àwọn ọ̀rọ̀ àdéhùn '''[[{{int:wm-license-gfdl-wiki-link}}|GNU Free Documentation License]]''', Version 1.3 gẹ́gẹ́bí wọ́n ṣe ti jẹ́ títẹ̀jáde lát'ọwọ́ [[{{int:wm-license-fsf-wiki-link}}|Free Software Foundation]] nìkan; láìsí àwọn Ẹsẹ Aláìyàtọ̀, láìsí àwọn Ọ̀rọ̀-ìwé Níwájú, àti láìsí Ọ̀rọ̀-ìwé Lẹ́yìn. Àwòkọ ìwé àṣẹ náà jẹ́ sísopọ̀ mọ́ abala tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ ''[[{{int:wm-license-gfdl-full-1.3-link}}|GNU Free Documentation License]]''.",
	"wm-license-gpl-text": "Iṣẹ́ yìí jẹ́  [[{{int:wm-license-free-software-wiki-link}}|atòlànà kọ̀mpútà ọ̀fẹ́]]; ẹ le ṣàtúnpínkiri rẹ̀ àti/tàbí ṣàtúnṣe rẹ̀ lábẹ́ àwọn ọ̀rọ̀ àdéhùn  '''[[{{int:wm-license-gpl-wiki-link}}|GNU General Public License]]''' gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti jẹ́ títẹ̀jáde látọwọ́ [[{{int:wm-license-fsf-wiki-link}}|Free Software Foundation]]; bóyá ó jẹ́ Ìwé-àṣẹ àtẹ̀jáde 2 tàbí àtẹ̀jáde ọjọ́ọwájú yìọ́wù. Iṣẹ́ yìí jẹ́ pípínkákiri pẹ̀lú ìrètí pé yí ò wúlò, sùgbọ́n '''lái sí ìdọ́jàpadà'''; láìsí ìdọ́jàpadà '''ìdúnàdúrà''' tàbí '''ìṣemímúlò fún ohun pàtó kan''' gan. Ẹ wo  [{{int:wm-license-gpl-2-full-link}} àtẹ̀jáde 2] àti [{{int:wm-license-gpl-3-full-link}} àtẹ̀jáde 3 ti GNU General Public License] fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́.",
	"wm-license-information-description": "Ìjúwe",
	"wm-license-information-description-missing": "Fáìlì yìí kò ní '''ìjúwe''', ó sì le mọ́n nìí ìwífún míràn.",
	"wm-license-information-source": "Orísun",
	"wm-license-information-date": "Ọjọ́ọdún",
	"wm-license-information-author": "Olùdá",
	"wm-license-information-permission": "Ìyọ̀nda",
	"wm-license-information-permission-reusing-text": "Ìtúnlò fáìlì yìí",
	"wm-license-information-permission-see-below": "Ẹ wo ìsàlẹ̀.",
	"wm-license-information-other-versions": "Àwọn àtẹ̀jáde míràn",
	"wm-license-licensing-update-text": "Àlẹ̀mọ́ ìwé àṣẹ yìí jẹ́ lílẹ̀mọ́ fáìlí yìí gẹ́gẹ́ bíi apá GFDL [[{{int:wm-license-licensing-update-wiki-link}}|ìṣọdọ̀tun ìwé àṣẹ]].",
	"wm-license-own-work": "Iṣẹ́ onítọ̀hún",
	"wm-license-pd-author-self-text": "Èmi gangan, tó jẹ́ pé èmi ni mo ni ẹ̀tọ́àwòkọ iṣẹ́ yìí, jọ̀wọ́ ìṣẹ́ yìí sínú '''[[{{int:wm-license-pd-wiki-link}}|ìgboro]]'''. Èyí kan gbogbo ayé.",
	"wm-license-pd-usgov-military-air-force-wiki-link": "w:yo:Iṣẹ́ Ològun Òfurufú Amẹ́ríkà",
	"wm-license-self-one-license": "Èmi gangan, tó jẹ́ pé èmi ni mo ni ẹ̀tọ́àwòkọ iṣẹ́ yìí, fara mọ́ ọ láti tẹ̀ẹ́jáde lábẹ́ ìwé-àṣẹ ìsàlẹ̀ yìí:",
	"wm-license-self-one-license-with-author": "$1, tó ni ẹ̀tọ́àwòkọ iṣẹ́ yìí, fara mọ́ ọ láti tẹ̀ẹ́jáde lábẹ́ ìwé-àṣẹ ìsàlẹ̀ yìí:",
	"wm-license-self-multiple-licenses": "Èmi gangan, tó jẹ́ pé èmi ni mo ni ẹ̀tọ́àwòkọ iṣẹ́ yìí, fara mọ́ ọ láti tẹ̀ẹ́jáde lábẹ́ àwọn ìwé-àṣẹ ìsàlẹ̀ yìí:",
	"wm-license-self-multiple-licenses-with-author": "$1, tó ni ẹ̀tọ́àwòkọ iṣẹ́ yìí, fara mọ́ ọ láti tẹ̀ẹ́jáde lábẹ́ àwọn ìwé-àṣẹ ìsàlẹ̀ yìí:",
	"wm-license-self-multiple-licenses-select": "Ẹ le ṣàmúyàn ìwé-àṣẹ tí ó wù yín."
}
