{
	"@metadata": {
		"authors": [
			"Demmy",
			"Nemo bis",
			"Wikicology"
		]
	},
	"wikimediamessages-desc": "Àwọn ìránṣẹ́ Wikimedia nìkan",
	"sitesupport-url": "https://donate.wikimedia.org/?utm_source=donate&utm_medium=sidebar&utm_campaign=spontaneous&uselang=yo",
	"sitesupport": "Ṣe ìgbọ̀wọ́",
	"tooltip-n-sitesupport": "Tíwá lẹ́yìn",
	"group-flood-member": "{{GENDER:$1|oníṣe bot}}",
	"grouppage-founder": "{{ns:project}}:Àwọn olùdásílẹ̀",
	"group-sysadmin": "Àwọn olùmójútó sístẹ́mù",
	"group-sysadmin-member": "{{GENDER:$1|olùmójútó sístẹ́mù}}",
	"wikimedia-copyright": "Gbogbo ìkọ wà lábẹ́ <a href=\"https://creativecommons.org/licenses/by-sa/3.0/\">Creative Commons Attribution-ShareAlike License</a>; ó ṣe é ṣe kí àwọn ọ̀rọ̀ àdéhùn míràn ó tún wà.\nẸ wo <a href=\"https://foundation.wikimedia.org/Terms_of_Use\">Àwọn Ọ̀rọ̀ Àdéhùn Ìlò</a> fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́.",
	"wikimedia-copyrightwarning": "Nípa mímúpamọ́, ẹ gbà láláìṣeédápadà láti fi àfikún yín sílẹ̀ lábẹ́ [https://creativecommons.org/licenses/by-sa/3.0/ Creative Commons Attribution-ShareAlike License 3.0] àti [https://www.gnu.org/copyleft/fdl.html GFDL].\nẸ gbà kí àwọn olùtúnlò míràn, o kéréjù pelú ìjápò tàbí URL sí ojúewé tí ẹ ṣàfikún sí, pe kí wọn ó dárúkọ yín.\nẸ wo [https://foundation.wikimedia.org/wiki/Special:MyLanguage/Terms_of_Use Àwọn Ọ̀rọ̀ Àdéhùn Ìlò] fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́.",
	"wikibase-sitelinks-wikinews": "Wikinews",
	"wikibase-sitelinks-wikiquote": "Wikiquote",
	"wikibase-sitelinks-wikisource": "Wikisource",
	"wikibase-sitelinks-wikivoyage": "Wikivoyage",
	"wikimedia-developers": "Àwọn olùgbédàgbà",
	"wikimedia-globalblocking-ipblocked": "'''Àdírẹ́sì IP rẹ ti jẹ́ [[m:Special:MyLanguage/Global blocks|dídílọ́nà lórí gbogbo àwọn wiki]].'''\n\nÌdínà rẹ wá lọ́wọ́ $1 ($2).\nÌdí tó wí nipé ''$3''.\n\n*Ìbẹ̀rẹ̀ ìdínà: $4\n*Ìparí ìdínà: $5\n\nÀdírẹ́sì IP rẹ yìí ni $6.\nJọ̀wọ́ fi gbogbo ọ̀kọ̀ọ̀kan òkè yìí sínú ìbérè tí o bá ṣe.\n\nTí o bá nígbàgbọ̀ pé ìdínà rẹ ṣẹlẹ̀ nítorí áṣìṣe, o le wo àfitétí míràn nínú ìpinu [[m:Special:MyLanguage/No open proxies|No open proxies]] gbogbo orí àwọn wiki.\nBíbẹ́ẹ̀kọ́, láti fọ̀rọ̀wérọ̀ nípa ìdínà náà jọ̀wọ́ [[m:Steward requests/Global|ṣe ìtọrọ fún àtúnyẹ̀wò lórí Meta-Wiki]].",
	"wikimedia-globalblocking-ipblocked-xff": "'''Ìkan tàbí ọ̀pọ̀ àwọn ẹ̀rọ ìwọ̀fà bojuboju tí o lò láti fi ṣe ìtọrọ rẹ ti jẹ́ [[m:Special:MyLanguage/Global blocks|dídílọ́nà lórí gbogbo àwọn wiki]].'''\n\nÌdínà rẹ wá lọ́wọ́ $1 ($2).\nÌdí tó wí nipé ''$3''.\n\n*Ìbẹ̀rẹ̀ ìdínà: $4\n*Ìparí ìdínà: $5\n\nÀdírẹ́sì ẹ̀rọ ìwọ̀fà bojuboju náà ni $6.\nJọ̀wọ́ fi gbogbo ọ̀kọ̀ọ̀kan òkè yìí sínú ìbérè tí o bá ṣe.\n\nTí o bá nígbàgbọ̀ pé ìdínà rẹ ṣẹlẹ̀ nítorí áṣìṣe, o le wo àfitétí míràn nínú ìpinu [[m:Special:MyLanguage/No open proxies|No open proxies]] gbogbo orí àwọn wiki.\nBíbẹ́ẹ̀kọ́, láti fọ̀rọ̀wérọ̀ nípa ìdínà náà jọ̀wọ́ [[m:Steward requests/Global|ṣe ìtọrọ fún àtúnyẹ̀wò lórí Meta-Wiki]]."
}
